support@yorubalibrary.com
+2348073529208, 07038599574
Iroko is one of the evergreen trees found in Nigeria. The tree is often referred to as "Iroko Oluwere" in Yoruba saying. This tree is popularly known for it hardness and used for different types of things including building construction, furniture making, hardwood exportation etc. Today, we will explore top 10 proverbs associated with this tree.
PROVERBS ASSOCIATED WITH IROKO TREE
1) Okere gun ori iroko, oju ode da
2) Kekere lati n pekan iroko, ti o ba d'agba tan, a maa gb'ebo
3) Omode bu Iroko, o b'oju weyin, se oojo ni oluwere n pani
4) Aso Iroko o see fi bora
5) O ko ba isin mawo, o o ba iroko mule, abere re bo somi, o ni o o yo.
6) Bi omode ba dari s'apa, apa a pa; bo o ba dari so iroko, iroko a koo l'ona.
7) Alangba to ja latori iroko ti k of'ese se, o ni bi enikan o yin un, oun o yin ara oun.
8) Bi Sango ba n pa araba, to n fa iroko ya, bii tigi nla ko
9) Ko wo, ko wo, araba o wo mo; oju ti'roko
10) Ibaa tirin, okun otito kii ja; bi iro ba to bi to iroko, wiwo ni n wo
If you know any other proverbs associated with Iroko Tree, you can use the comment section below...